Tẹsalonika Keji 1:10 BM

10 nígbà tí Oluwa bá dé ní ọjọ́ náà láti gba ògo lọ́dọ̀ àwọn ẹni mímọ́ rẹ̀, nígbà tí gbogbo àwọn tí ó gbàgbọ́ yóo máa yẹ́ ẹ sí, nítorí wọ́n gba ẹ̀rí tí a jẹ́ fún wọn gbọ́.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 1

Wo Tẹsalonika Keji 1:10 ni o tọ