12 kí ẹ lè yin orúkọ Oluwa wa Jesu lógo, kí òun náà sì yìn yín, gẹ́gẹ́ bí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọrun wa ati ti Oluwa Jesu Kristi.
Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 1
Wo Tẹsalonika Keji 1:12 ni o tọ