Tẹsalonika Keji 2:12 BM

12 kí gbogbo àwọn tí kò gba òtítọ́ gbọ́ lè gba ìdálẹ́bi, àní, àwọn tí wọ́n ní inú dídùn sí ìwà ibi.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 2

Wo Tẹsalonika Keji 2:12 ni o tọ