Tẹsalonika Keji 3:15 BM

15 Ẹ má mú un lọ́tàá, ṣugbọn ẹ máa gbà á níyànjú bí onigbagbọ.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Keji 3

Wo Tẹsalonika Keji 3:15 ni o tọ