12 Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Kristi Jesu Oluwa wa, ẹni tí ń fún mi ní agbára. Mo dúpẹ́ nítorí ó kà mí yẹ láti fún mi ní iṣẹ́ rẹ̀,
Ka pipe ipin Timoti Kinni 1
Wo Timoti Kinni 1:12 ni o tọ