Timoti Kinni 2:15 BM

15 Ṣugbọn a óo gba obinrin là nípa ọmọ-bíbí, bí àwọn obinrin bá dúró láì yẹsẹ̀ ninu igbagbọ ati ìfẹ́ ati ìwà mímọ́ pẹlu ìwà ìkóra-ẹni-níjàánu.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 2

Wo Timoti Kinni 2:15 ni o tọ