Timoti Kinni 2:6 BM

6 tí ó fi ara rẹ̀ ṣe ìràpadà fún gbogbo eniyan. Èyí ni ẹ̀rí pé, Ọlọrun ṣe ètò pé kí gbogbo eniyan lè ní ìgbàlà nígbà tí àkókò rẹ̀ tó.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 2

Wo Timoti Kinni 2:6 ni o tọ