12 Diakoni kò gbọdọ̀ ní ju aya kan lọ; ó sì gbọdọ̀ káwọ́ àwọn ọmọ rẹ̀ dáradára ati gbogbo ìdílé rẹ̀.
Ka pipe ipin Timoti Kinni 3
Wo Timoti Kinni 3:12 ni o tọ