Timoti Kinni 4:4 BM

4 Nítorí ohun gbogbo tí Ọlọrun dá ni ó dára. Kò sí ohun tí a gbọdọ̀ kọ̀ bí a bá gbà á pẹlu ọpẹ́,

Ka pipe ipin Timoti Kinni 4

Wo Timoti Kinni 4:4 ni o tọ