Timoti Kinni 5:11 BM

11 Ṣọ́ra nípa kíkọ orúkọ àwọn opó tí wọ́n jẹ́ ọ̀dọ́ sílẹ̀, nítorí nígbà tí ara wọn bá gbóná, wọn yóo kọ ètò ti Kristi sílẹ̀, wọn yóo fẹ́ tún lọ́kọ.

Ka pipe ipin Timoti Kinni 5

Wo Timoti Kinni 5:11 ni o tọ