25 Bákan náà ni, iṣẹ́ rere a máa hàn sí gbogbo eniyan. Bí wọn kò bá tilẹ̀ tíì hàn, wọn kò ṣe é bò mọ́lẹ̀ títí.
Ka pipe ipin Timoti Kinni 5
Wo Timoti Kinni 5:25 ni o tọ