Timoti Kinni 5:9 BM

9 Má kọ orúkọ ẹnikẹ́ni sílẹ̀ bí opó àfi ẹni tí ọjọ́ orí rẹ̀ kò bá dín ní ọgọta ọdún, tí ó sì jẹ́ aya ọkọ kan,

Ka pipe ipin Timoti Kinni 5

Wo Timoti Kinni 5:9 ni o tọ