Hab 1:15 YCE

15 Iwọ ni àwọn lati fi gbé gbogbo wọn, nwọn nfi àwọn mu wọn, nwọn si nfi awò wọn kó wọn: nitorina ni nwọn ṣe nyọ̀, ti inu wọn si ndùn.

Ka pipe ipin Hab 1

Wo Hab 1:15 ni o tọ