Hab 3:2 YCE

2 Oluwa, mo ti gbọ́ ohùn rẹ, ẹ̀ru si bà mi: Oluwa, mu iṣẹ rẹ sọji lãrin ọdun, lãrin ọdun sọ wọn di mimọ̀; ni ibinu ranti ãnu.

Ka pipe ipin Hab 3

Wo Hab 3:2 ni o tọ