Hag 2:6 YCE

6 Nitori bayi ni Oluwa awọn ọmọ-ogun wi, pe, Ẹ̃kan ṣa, nigbà diẹ si i, li emi o mì awọn ọrun, ati aiye, ati okun, ati iyàngbẹ ilẹ.

Ka pipe ipin Hag 2

Wo Hag 2:6 ni o tọ