Joel 1:4 YCE

4 Eyi ti iru kòkoro kan jẹ kù ni ẽṣú jẹ; ati eyi ti ẽṣú jẹ kù ni kòkoro miràn jẹ; eyiti kòkoro na si jẹ kù ni kòkoro miràn jẹ.

Ka pipe ipin Joel 1

Wo Joel 1:4 ni o tọ