5 Ji, ẹnyin ọmùti, ẹ si sọkun; si hu, gbogbo ẹnyin ọmùti waini, nitori ọti-waini titun; nitoriti a ké e kuro li ẹnu nyin.
Ka pipe ipin Joel 1
Wo Joel 1:5 ni o tọ