Jon 2:4 YCE

4 Nigbana ni mo wipe, A ta mi nù kuro niwaju rẹ; ṣugbọn sibẹ emi o tun ma wo iha tempili mimọ́ rẹ.

Ka pipe ipin Jon 2

Wo Jon 2:4 ni o tọ