Mal 2:8 YCE

8 Ṣugbọn ẹnyin ti yapa kuro li ọ̀na na: ẹnyin ti mu ọ̀pọlọpọ kọsẹ ninu ofin; ẹnyin ti ba majẹmu Lefi jẹ, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.

Ka pipe ipin Mal 2

Wo Mal 2:8 ni o tọ