Mal 3:3 YCE

3 On o si joko bi ẹniti nyọ́, ti o si ndà fadakà: yio si ṣe awọn ọmọ Lefi mọ́, yio si yọ́ wọn bi wurà on fadakà, ki nwọn ki o le mu ọrẹ ododo wá fun Oluwa.

Ka pipe ipin Mal 3

Wo Mal 3:3 ni o tọ