Mal 4:3 YCE

3 Ẹnyin o si tẹ̀ awọn enia buburu mọlẹ: nitori nwọn o jasi ẽrú labẹ atẹlẹsẹ̀ nyin, li ọjọ na ti emi o dá, li Oluwa awọn ọmọ-ogun wi.

Ka pipe ipin Mal 4

Wo Mal 4:3 ni o tọ