Rut 2:10 YCE

10 Nigbana ni o wolẹ, o si tẹ̀ ara rẹ̀ ba silẹ, o si wi fun u pe, Eṣe ti mo ri ore-ọfẹ li oju rẹ, ti iwọ o fi kiyesi mi, bẹ̃ni alejo li emi?

Ka pipe ipin Rut 2

Wo Rut 2:10 ni o tọ