Rut 2:23 YCE

23 Bẹ̃li o faramọ́ awọn ọmọbinrin ọdọ Boasi lati ma peṣẹ́-ọkà titi ipari ikore ọkà-barle ati ti alikama; o si wà lọdọ iya-ọkọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Rut 2

Wo Rut 2:23 ni o tọ