Efe 1:18 YCE

18 Ki oju ọkàn nyin le mọlẹ; ki ẹnyin ki o le mọ ohun ti ireti ìpe rẹ̀ jẹ, ati ohun ti ọrọ̀ ogo ini rẹ̀ ninu awọn enia mimọ́ jẹ,

Ka pipe ipin Efe 1

Wo Efe 1:18 ni o tọ