Efe 3:16 YCE

16 Ki on ki o le fifun nyin, gẹgẹ bi ọrọ̀ ogo rẹ̀, ki a le fi agbara rẹ̀ mú nyin li okun nipa Ẹmí rẹ̀ niti ẹni inu;

Ka pipe ipin Efe 3

Wo Efe 3:16 ni o tọ