Efe 5:8 YCE

8 Nitori ẹnyin ti jẹ òkunkun lẹ̃kan, ṣugbọn nisisiyi, ẹnyin di imọlẹ nipa ti Oluwa: ẹ mã rìn gẹgẹ bi awọn ọmọ imọlẹ:

Ka pipe ipin Efe 5

Wo Efe 5:8 ni o tọ