Efe 6:8 YCE

8 Bi ẹnyin ti mọ pe ohun rere kohunrere ti olukuluku ba ṣe, on na ni yio si gbà pada lọdọ Oluwa, ibã ṣe ẹrú, tabi omnira.

Ka pipe ipin Efe 6

Wo Efe 6:8 ni o tọ