Filp 2:26 YCE

26 Nitoriti ọkàn rẹ̀ fà si gbogbo nyin, o si kún fun ibanujẹ, nitoriti ẹnyin ti gbọ́ pe on ti ṣe aisan.

Ka pipe ipin Filp 2

Wo Filp 2:26 ni o tọ