Filp 3:15 YCE

15 Nitorina, ẹ jẹ ki iye awa ti iṣe ẹni pipé ni ero yi: bi ẹnyin bá si ni ero miran ninu ohunkohun, eyi na pẹlu ni Ọlọrun yio fi hàn nyin.

Ka pipe ipin Filp 3

Wo Filp 3:15 ni o tọ