Filp 3:5 YCE

5 Ẹniti a kọ nilà ni ijọ kẹjọ, lati inu kukuté Israeli wá, lati inu ẹ̀ya Benjamini, Heberu lati inu Heberu wá; niti ofin, Farisi li emi;

Ka pipe ipin Filp 3

Wo Filp 3:5 ni o tọ