1. Joh 2:1 YCE

1 ẸNYIN ọmọ mi, iwe nkan wọnyi ni mo kọ si nyin, ki ẹ má bã dẹṣẹ̀. Bi ẹnikẹni ba si dẹṣẹ̀, awa ni alagbawi lọdọ Baba, Jesu Kristi olododo:

Ka pipe ipin 1. Joh 2

Wo 1. Joh 2:1 ni o tọ