1. Joh 2:29 YCE

29 Bi ẹnyin ba mọ̀ pe olododo ni on, ẹ mọ̀ pe a bi olukuluku ẹniti nṣe ododo nipa rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Joh 2

Wo 1. Joh 2:29 ni o tọ