1. Joh 4:1 YCE

1 OLUFẸ, ẹ máṣe gbà gbogbo ẹmí gbọ́, ṣugbọn ẹ dán awọn ẹmí wò bi nwọn ba ṣe ti Ọlọrun: nitori awọn woli eke pupọ̀ ti jade lọ sinu aiye.

Ka pipe ipin 1. Joh 4

Wo 1. Joh 4:1 ni o tọ