1. Joh 4:10 YCE

10 Ninu eyi ni ifẹ wà, kì iṣe pe awa fẹ Ọlọrun, ṣugbọn on fẹ wa, o si rán Ọmọ rẹ̀ lati jẹ ètutu fun ẹ̀ṣẹ wa.

Ka pipe ipin 1. Joh 4

Wo 1. Joh 4:10 ni o tọ