2. Joh 1:1 YCE

1 EMI alàgba si ayanfẹ obinrin ọlọlá ati awọn ọmọ rẹ̀, awọn ti mo fẹ li otitọ; kì si iṣe emi nikan, ṣugbọn gbogbo awọn ti o mọ̀ otitọ pẹlu;

Ka pipe ipin 2. Joh 1

Wo 2. Joh 1:1 ni o tọ