2. Joh 1:7 YCE

7 Nitori ẹlẹtàn pupọ̀ ti jade wá sinu aiye, awọn ti kò jẹwọ pe Jesu Kristi wá ninu ara. Eyi li ẹlẹtàn ati Aṣodisi Kristi.

Ka pipe ipin 2. Joh 1

Wo 2. Joh 1:7 ni o tọ