12 Ki a le yìn orukọ Jesu Oluwa wa logo ninu nyin, ati ẹnyin ninu rẹ̀, gẹgẹ bi ore-ọfẹ Ọlọrun wa ati ti Jesu Kristi Oluwa.
Ka pipe ipin 2. Tes 1
Wo 2. Tes 1:12 ni o tọ