2. Tes 3:16 YCE

16 Njẹ ki Oluwa alafia tikararẹ̀ mã fun nyin ni alafia nigbagbogbo lọna gbogbo. Ki Oluwa ki o pẹlu gbogbo nyin.

Ka pipe ipin 2. Tes 3

Wo 2. Tes 3:16 ni o tọ