2. Tim 1:3 YCE

3 Mo dupẹ lọwọ Ọlọrun, ti emi nsìn lati ọdọ awọn baba mi wá ninu ẹri-ọkan funfun, pe li aisimi li emi nṣe iranti rẹ ninu adura mi,

Ka pipe ipin 2. Tim 1

Wo 2. Tim 1:3 ni o tọ