14 Nkan wọnyi ni ki o mã rán wọn leti, mã kìlọ fun wọn niwaju Oluwa pe, ki nwọn ki o máṣe jijà ọ̀rọ ti kò lere, fun iparun awọn ti ngbọ.
Ka pipe ipin 2. Tim 2
Wo 2. Tim 2:14 ni o tọ