2. Tim 4:16 YCE

16 Li àtetekọ jẹ ẹjọ mi, kò si ẹniti o bá mi gba ẹjọ ro, ṣugbọn gbogbo enia li o kọ̀ mi silẹ: adura mi ni ki a máṣe kà a si wọn li ọrùn.

Ka pipe ipin 2. Tim 4

Wo 2. Tim 4:16 ni o tọ