Jak 1:22 YCE

22 Ṣugbọn ki ẹ jẹ oluṣe ọ̀rọ na, ki o má si ṣe olugbọ́ nikan, ki ẹ mã tàn ara nyin jẹ.

Ka pipe ipin Jak 1

Wo Jak 1:22 ni o tọ