Jak 3:17 YCE

17 Ṣugbọn ọgbọ́n ti o ti oke wá, a kọ́ mọ́, a si ni alafia, a ni ipamọra, kì isí iṣoro lati bẹ̀, a kún fun ãnu ati fun eso rere, li aisi ègbè, ati laisi agabagebe.

Ka pipe ipin Jak 3

Wo Jak 3:17 ni o tọ