Jak 3:3 YCE

3 Bi a bá si fi ijanu bọ̀ ẹṣin li ẹnu, ki nwọn ki o le gbọ́ ti wa, gbogbo ara wọn li awa si nyi kiri pẹlu.

Ka pipe ipin Jak 3

Wo Jak 3:3 ni o tọ