Jak 4:9 YCE

9 Ki inu nyin ki o bajẹ, ki ẹ si gbàwẹ, ki ẹ si mã sọkun: ẹ jẹ ki ẹrín nyin ki o di àwẹ, ati ayọ̀ nyin ki o di ikãnu.

Ka pipe ipin Jak 4

Wo Jak 4:9 ni o tọ