Jud 1:16 YCE

16 Awọn wọnyi li awọn ti nkùn, awọn alaroye, ti nrìn nipa ifẹkufẹ ara wọn; ẹnu wọn a mã sọ ọ̀rọ ìhalẹ, nwọn a mã ṣojuṣãjú nitori ere.

Ka pipe ipin Jud 1

Wo Jud 1:16 ni o tọ