Kol 4:8 YCE

8 Ẹniti mo ti rán si nyin nitori eyi kanna, ki ẹnyin le mọ̀ bi a ti wà, ki on ki o le tù ọkàn nyin ninu;

Ka pipe ipin Kol 4

Wo Kol 4:8 ni o tọ