Ẹkún Jeremáyà 2:19 BMY

19 Dìde, kígbe sókè ní àsálẹ́,bí ìṣọ́ òru ti bẹ̀rẹ̀tú ọkàn rẹ̀ jáde bí ominíwájú Olúwa.Gbé ọwọ́ yín sókè sí inítorí ẹ̀mí àwọn èwe rẹ̀tí ó ń kú lọ nítorí ebiní gbogbo oríta òpópó.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2

Wo Ẹkún Jeremáyà 2:19 ni o tọ