20 “Wòó, Olúwa, kí o sì rò ó:Ta ni ìwọ ti fìyà jẹ bí èyíǸjẹ́ àwọn obìnrin yóò ha jẹ ọmọ wọn,àwọn ọmọ tí wọn ń se ìtọ́jú fún?Ǹjẹ́ kí a pa olórí àlùfáà àti àwọn wòlíìní ibi mímọ́ Olúwa?
Ka pipe ipin Ẹkún Jeremáyà 2
Wo Ẹkún Jeremáyà 2:20 ni o tọ