Hágáì 1:1 BMY

1 Ní ọdún kejì ọba Dáríúsì ní ọjọ́ kìn-ín ní okìn-ín-ní oṣù kẹfà, ọ̀rọ̀ Olúwa wá nípasẹ̀ wòlíì Hágáì sí Serubábéli ọmọ Séítélì, Baálẹ̀ Júdà, àti Sọ́dọ̀ Jósúà ọmọ Jósédékì, olórí àlùfáà.

Ka pipe ipin Hágáì 1

Wo Hágáì 1:1 ni o tọ